Igba meta gbako ni ina monamona odoTiwa Savageku mo wa loju nigbati a nse ipade l’ori ero ayelujara.

Bee ni won nsaajo ni mesan-mewa, “E ma binu bi ina se nku mowa loju.”

Oro won kuku ye mi, awa mejeeji lajo wa ni Ila Oorun Africa.

Image may contain Graphics Art Floral Design Pattern and Text

Kii se ohun titun wipe Ina monamona ma nse monamona ni awon oluilu to wa ni Africa.

Mo fe ko imo nipa ibi ti iya mi ti to wa.

Nise ni awo ara won, ti won fi bronzer feerefe kun, ndan bii fadaka.

Image may contain Magazine Human and Person

Kaba IAMISIGO Floribunda. Tiffany & Co. Yerí. Láti ṣe irú oge yìí: Face Illuminator Highlighting Powder in Seduction, Lip Glacé in Bare Blush, and Longer Lip Liner in Red Chocolate by Laura Mercier.

Won ti gba orisirisi oriyin fun awon ise won, ogunlogo eniyan lo si ma nwo awon fidio won.

Lagos State ni orile-ede Nigeria la bi Tiwatope Savage si.

Sugbon awon obi won kuku fi ye won wipe won gbodo koko mu iwe kika ni okunkundun.

Image may contain Face Human Person Plant Head Flower Blossom Smile and Rose

Kaba IAMISIGO Floribunda. Tiffany & Co. Yerí. Láti ṣe irú oge yìí: Face Illuminator Highlighting Powder in Seduction, Lip Glacé in Bare Blush, and Longer Lip Liner in Red Chocolate by Laura Mercier.

Nitori idi eleyii ni won se gba degree accounting lati ile iwe giga ti Unifasiti Kent.

Ninu iforowanilenuwo won pelu Hot 97, Savage ranti oun ti awon obi re so.

Savage tun yanana oro naa siwaju sii.

Nigerian musician Tiwa Savage dances for the camera wearing a floorlength peach fringe dress. Her hair is in two braids…

Kaba IAMISIGO Floribunda

Tiffany & Co. Yeri.

Inu ko tile bi won.

Sugbon inu won ko dun si mi rara, oju de gba won ti fun mi.

Nitori naa won se atunto.

A ni lati wa awon eeyan ti ko sebi wipe awon ti d’ape ju.

Mo mo wipe gbogbo wa la fe gbayi lawujo, a si feran oge.

Nje lara ifiraeni han, gba mi bi mo se ri, won ni ipinnu yii?

Emi naa wa pinnu lati ma lo iyefun-atele mo."

Sugbon fun Savage oun ti o wuun ni ati da wahala ohun koja.

Ise ara eni loge, bii irin ajo aye won nisisiyii, gbodo je itura.

Won nso fun omo won wipe “Baba e tuntun lo nwo yen.”

Bi won se nwo Legend of the Blue Sea).

Won tun nro bi won se ma fi oro to ni opolopo laakaye si inu orin won.

Aimoye igba ni awon oloselu ati olori esin binu si orin Savage ti o nba jegudu-jera wi.

Irawo agbaye Afrobeats fun wa ni oro kinkin to gbankogbi nje o ti lo ose dudu lati Africa ri?

akape ohun amusewa tiwantiwa to feran.

Mo ma npo ataale ati oyin po, maa si fi pa oju fun bii iseju marudinlogun.

To read this story in English,click here.